YIYO EKUN :
La prudence du léopard. (En langue yoruba)
Paroles
Yiyo ekun ojo ko rara o} 4mes
Ekun lanu sile gbaragada
Ekun lanu sile o nwo susu
Igala nkoja ekun o gbin
Okete nkoja ekun o dahun o
Yiyo ekun ojo ko rara
Ebi o p’ekun ni o se dide }2ce Backvocal [Yiyo ekun ojo ko o]
Oni lanu sile o ngb’ategun mi
O gan sibi kan bi eni to nsun
Esinsin nkoja oni o dahun o
Eranko nkoja oni o tie gbin
Yiyo ekun ojo ko rara
Suru l’oni nlo to fi np’eran o Backvocal [Yiyo ekun ojo ko o]
Ere nla to na sile gbagidi
T’oya nsere nitosi t’ere o gbin
Okere nsere ere se bi eni to nsun
Ere ti yo ni o se dahun o
Yiyo ekun ojo ko rara
Ebi o p’ere ni o se dide }2ce Backvocal [Yiyo ekun ojo ko o]
Igbati kiniun joko sabe igi
To ngb’ategun alafia sara
T’oya nkoja t‘okete nsere
Beni malu njo o t’aguntan nkorin
Yiyo ekun ojo ko rara
Ebi o pa kiniu ni o dide }2ce Backvocal [Yiyo ekun ojo ko o]
Yiyo ekun o ojo ko rara Backvocal [Yiyo ekun ojo ko o]
Suru l’ekun nlo to fi nsode
Suru nigi nlo to fi nhu ewe
Suru lodo nlo to fi nsan o
Suru l’olode nlo to ba lo s’igbo
Suru l’eniyan fi nje nkan to gbona
Suru l’oba nlo oba ki l’agidi
Suru l’agba nlo t’omo re fi npo si
(Ne méprenez pas la prudence du léopard
pour de la lâcheté, tout s’accomplir avec la patience.)