O DIGBOSE
(ADIEU)/ (FAREWELL)
(chanson en hommage à ma mère en yoruba)
(a tribute to my late mother in yoruba)
Paroles
Ojumo mo oun o gbo poroporo odo
Ojumo mo oun o gbo kisa kisa kankan sa
Ojumo mo oun gbo pese pese ese nle
Ojumo mo oun o gbo sinrin sinrin omi odo
Ojumo mo oun oun o gb’ohun ya mi, Moyosola omo Akinsunroju
Akinkanju mama, akinkanju obinrin meje
Iya mi ti rebi agba nre, Iya mi ti file saso bora
Refrain : O digbose backvocals [Arinako o digbose arinako] }4mes
Ka to r’erin o digbo o
Ka to r’efon o d’ona
Ka to r’oba o dile o
To ba dele ko ki le, to ba d’ona ko bere o
Refrain
Iku ko m’omode o, Iku ko m’onile
Iku ko malejo o, Iku ko m’agba se
Refrain
Eye to fo lana, Erin to nfon ninu nigbo
Oni to nwemi odo, ode to re gbo eran pipa
Akinkanju to jagun wale
Bo di jo kan kan kan
Refrain
Bodi jo kan a o reye mo
Oni ko ni wemi mo
Ode o ni re gbo eran pipa mo o
Balogun o ni jagun wale mo
Erin ko ni fon n’igbo mo
O digbose
Refrain O doju ala, o dijo mi ojo re
O digbose
Ka to r’Erin o d’igbo o, ka to r’Efon o dona o O datun pade
Ka to r’eye o doke orun O datun rari
Ka to to ri kiniun oba igbo, ka to r’eja nla nisale okun O di gbere o darinako
Ka to r’orun ti o sun lale o, ka to r’osupa osan gangan
Refrain